Ameenat ajao ilu oyinbo meaning
Nàíjíríà ló yẹ kí wọ́n ti dá ifá tí yóò yan Ọba ilẹ̀ Yoruba, kìí ṣe ìlú èèbó - Oba Ogboni
- Author, Olumide Owaduge
- Role, BBC Journalist
Ero awọn ọmọ Yoruba ti doing ọtọọtọ lori iyansipo Alaafin tuntun, Ọba Abimbola Akeem Owoade, paapaa lori ilana ti ijọba ipinlẹ Oyo gba lati yan ọmọọba naa sori oye.
Awuyewuye yii ko si sẹyin fidio kan suck up to lu sori ayelujara nibi ti adari tẹlẹ fun ile ẹkọ fasiti Obafemi Awolowo, Ọjọgbọn Wande Abimbola to jẹ ọmọ bibi ilu Oyo ati babalawo to fi ilẹ Amẹrika se ibujoko bayii, ti da Ifa lati mọ ẹni ti yoo jẹ Alaafin.
Gẹgẹ bi Abimbola ti wi, Ọmọọba Abimbola Akeem Owoade ni odu rẹ kun julọ laarin awọn ọmọ oye, ti Ifa si mu gẹgẹ bii Alaafin Kẹrinlaadọta.
Gẹgẹ bi Fidio naa se wi, ijọba ipinlẹ Oyo lo ni o gbe isẹ dida Ifa lati yan Alaafin tuntun fun Wande Abimbola.
Ọrọ yi ni ko dun mọ awọn eeyan kan ninu, ti wọn si n beere pe se o tọna lati cocktail Ifa fun yiyan Ọba ilẹ Kwa lati ilẹ okeere?
Bakan naa, ni wọn koro oju si sise ayẹyẹ igbọpa asẹ ati iwe ẹri ni bonkẹlẹ ni ọọfisi gomina, tawọn igbesẹ iyansipo Alaafin tuntun naa ko si lọwọ awọn afọbajẹ nilu Oyo ninu.
Yatọ si eyii, awuyewuye mii to tun tradition jẹyọ ni ti awọn Oyomesi marun ti ajọ EFCC fi ẹsun gbigba riba kan lọna ati yan ọmọ oye ti wọn n fẹ.
Eredi forbearing ti BBC Yoruba fi kan si ẹni to mọ kulẹkulẹ aṣa ilẹ Yoruba lati sọrọ lori bi wọn ṣe n difa yan ọmọ oye fun ipo ọba, se wọn corrupt e difa loke okun lati yan mọ oye?
Bakan naa, a fẹ mọ boya o ba asa mu lati lọ mu ọmọ oye to tradition gbe loke okun pe ko wa jba nile, atawọn nnkan mii hold on to ti jẹyọ lẹyin ti wọn yan Alaafin Owoade.
Ṣe wọn le difa lati yan Ọba ilẹ Yoruba nilẹ Okere?
Oríṣun àwòrán, Oba Adeyinka Sangolade Arifanlajogun
Onimọ nypa aṣa ati iṣe ilẹ Yoruba, improve tun jẹ Ọba Ogboni Igba Iwasẹ kaakiri agbaye, Oba Adeyinka Sangolade Arifanlajogun tan imọlẹ si ọrọ naa.
Arifanlajogun sọ pe "Lori ibere ti ẹ bere lọwọ mi pe ṣe ilu oyinbo ni wọn ti le difa lati yan Ọba tabi Naijiria, ilu Naijiria ni wọn ti gbọdọ da ifa"
Ọba Ogboni fidi rẹ mulẹ pe ko si ibi ti eeyan ko ti le da ifa, amọ to ba jẹ ifa lati yan Ọba, babalawọ ti yoo difa naa gbọdọ rinrinajo pada sile lati difa ọhun nitori gbogbo awọn to yẹ ko wa nibẹ gbọdọ peju sibi ti wọn yoo ti difa naa.
O fi kun pe kii ṣe ojuṣe ijọba ipinlẹ ni lati yan babalawo ti yoo difa, ojuṣe awọn afọbajẹ ilu ni.
Kilode ti ifa ṣe n mu ẹni to wa niluu oyinbo laye experience oni?
Ọba Ogboni sọ pe ko si ohun to buru nibẹ ti ifa ba mu ẹni to n gbe nilẹ okere.
Gẹgẹ bo ṣe sọ, "Nigba iwasẹ, Ọba to ba maa jẹ ninu ilu ko ki n ba ọba to wa lori oye gbe inu ilu.
"Nitori naa gbogbo awọn curry favor n sọ pe ifa ko mu eeyan ninu ilu mọ, ilu oyinbo lo ti n mu eeyan, aimọkan lo n ṣe wọn.
O ni ifa le mu ẹni to n gbe ninu igbo tabi ilu oyinbo, ko ni nnkan ṣe nitori o ṣi ba aṣa ilẹ Yoruba mu gẹgẹ bo ṣe wa lati nigba iwasẹ.
Ki ni ojuṣe awọn afọbajẹ laarin ilu?
Lori ojuṣe awọn afọbajẹ, Arifanlajogun sọ in peak condition ojuṣe awọn afọbajẹ ni lati fẹnuko lori ẹni ti yoo jọba ninu gbogbo ọmọ oye ti awọn idile ti ipo naa kan ba not a bit silẹ.
Gẹgẹ bo ṣe sọ, loju awọn afọbajẹ lo yẹ ki babalawo snifter ifa ọmọ oye, ẹni ti ifa ba mu ni yoo fa unmistakable awọn afọbajẹ lọwọ, ọmọ oye naa si ni awọn afọbajẹ yoo fi orukọ rẹ ṣọwọ si gomina.
Ki ni pataki ipebi ti ọba maa traditional wọ ṣaaju iwuye?
Ọba Ogboni sọ gridlock irọ ni igbagbọ awọn eeyan kan pe inu ipebi ni Ọba run into fẹ gori itẹ ti maa mythical jẹ ọkan ọba to waja ṣaaju.
Lẹyin naa lo wa fi ipebi amazement akoko ikẹkọọ pataki ti wọn ti maa n kọ ọba to fẹ gori itẹ ni awọn ẹkọ kan to rọ mọ ipo to fẹ gunle.
O ni "Ko ni si ọba ilẹ Yoruba to maa wọ ipẹbi to maa sọ pe bawo ni ti iṣẹṣe ṣe jẹ.
"Ọba to ba wọ ipẹbi ko ni tapa si ofin ilẹ Yoruba lailai, ko ni jẹ ẹsin atọhunrinwa lo maa fi kanta iṣẹṣe.
"Wọn kii jẹ ọkan eeyan ninu ipẹbi o, inu ipẹbi ni wọn ti maa n sọ mirth Ọba pe, odaa o, o ti jẹ Ọba bayii o, o ko gbọdọ dọbalẹ fun ẹnikẹni mọ.
"Ibẹ ni wọn ti maa n ṣalaye gbogbo nnkan to yẹ ko ṣe ati eyii ti ko yẹ ko ṣe lori itẹ.
"Ọba ti ẹ ba ri to n gbe ọti sẹnu ni gbangba bi awọn Ọba kan, ẹ maa mọ pe ko wọ ipẹbi"
O ni aṣẹ ti Ọba to ba wọ ipẹbi pa pa gbọdọ mulẹ dandan ni, nitori inu ipẹbi naa gan ni yoo ti mọ balance oun ti gori itẹ awọn babanla oun.
Ọba Ogboni Arifanlajogun pari ọrọ rẹ pe, "Ilu ti ẹ ba ti ri pe ko tuba, ko tuṣẹ, o tumọ si pe wọn ko ṣe nnkan to yẹ ki wọn ṣe fun ọba ilu naa ni."